Skip to main content

Posts

Showing posts from January, 2020
Happy birthday Ejire ara Isokun Edun A gbori igi regrege Winino winini loju orogun Eji woro loju iya e O be kisi be kese O be sile elekisa O so o dalaso Okan mo ni n o bi Eji lo wole to mi Bu mi ki nba o releYin mi ki npada leyin re Nijo ejire ti daye ko jale ri Oju oloko ni se je tie Mo lepo nile Mo lewa loode Ejire eelaki maa bo lodo mi Ireke mi ree Aadun mi ree Mo fe bo ibeji oro Oniruuru omo lo nbe laye Ninu omo to je abami